Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 19:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ ìmọ̀ tí ó kan Éjíbítì:Kíyèsíi, Olúwa gun àwọsánmọ̀ tí ó yára lẹ́sinó sì ń bọ̀ wá sí Éjíbítì.Àwọn ère òrìṣà Éjíbítì wárìrì níwájúu rẹ̀,ọkàn àwọn ará Éjíbítì sì ti domi nínú un wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 19

Wo Àìsáyà 19:1 ni o tọ