Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 18:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkókò náà ni a ó mú ẹ̀bùn wá fún Olúwa àwọn ọmọ-ogunláti ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn gíga tí ẹran ara wọn jọ̀lọ̀,láti ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn tí a bẹ̀rù níbi gbogbo,orílẹ̀ èdè aláfojúdi àti alájèjì èdè,ilẹ̀ ẹni tí omi pín sí yẹ́lẹyẹ̀lẹ—a ó mú àwọn ẹ̀bùn náà wá sí òkè Síónì, ibi tí orúkọ Olúwa àwọn ọmọ-ogun gbé wà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 18

Wo Àìsáyà 18:7 ni o tọ