Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 18:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ohun tí Olúwa sọ fún mi:“Èmi yóò dákẹ́ jẹ́ ẹ́, n ó sì máa wo òréréláti ibùgbé e mi wá,gẹ́gẹ́ bí ooru gbígbóná nínú ìtànsán òòrùn,gẹ́gẹ́ bí òjò-dídì ní àárin gbùngbùn ìkóórè.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 18

Wo Àìsáyà 18:4 ni o tọ