Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 17:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ náà àwọn ìlú alágbára wọn, tí wọ́n fi sílẹ̀ nítorí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, yóò dàbí ilẹ̀ tí a dà sílẹ̀ kó di ìgbòrò. Gbogbo wọn yóò sì di ahoro.

Ka pipe ipin Àìsáyà 17

Wo Àìsáyà 17:9 ni o tọ