Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 17:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kò ní wo àwọn pẹpẹ mọ́,èyí tí í ṣe iṣẹ́ ọwọ́ọ wọn,wọn kò sì ní kọbi ara sí òpó Áṣérà mọ́tàbí pẹpẹ tùràrí tí ìka ọwọ́ wọn ti ṣe.

Ka pipe ipin Àìsáyà 17

Wo Àìsáyà 17:8 ni o tọ