Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 17:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì dàbí ìgbà tí olùkóórè kó àwọnirúgbìn tí ó dúró jọtí ó sì ń kórè irúgbìn pẹ̀lú apá rẹ̀—àti gẹ́gẹ́ bí ìgbà tí ènìyàn pa ọkà ní àfonífojì ti Réfémù.

Ka pipe ipin Àìsáyà 17

Wo Àìsáyà 17:5 ni o tọ