Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 17:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, bí ẹ tilẹ̀ mú àsàyàn igi tí ẹ sì gbin àjàrà tí ó ti òkèrè wá,bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ọjọ́ tí ẹ kó wọn jáde ẹ mú wọn hú jáde,àti ní òwúrọ̀ tí ẹ gbìn wọ́nẹ mú kí wọ́n rúdí,ṣíbẹ̀ ṣíbẹ̀ ìkóórè kò ní mú nǹkan wání ọjọ́ àrùn àti ìrora tí kò gbóògùn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 17

Wo Àìsáyà 17:11 ni o tọ