Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 15:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn mi kígbe lórí Móábù;àwọn ìṣáǹṣá rẹ sálà títí dé Ṣóárì,títí fi dé Égílátì Ṣẹ́líṣíyà.Wọ́n gòkè lọ títí dé Lúhítìwọ́n ń ṣunkún bí wọ́n ti ń lọ,Ní òpópónà tí ó lọ sí Hórónáímùwọ́n ń pohùnréré ìparun wọn

Ka pipe ipin Àìsáyà 15

Wo Àìsáyà 15:5 ni o tọ