Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 15:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n wọ aṣọ ọ̀fọ̀ ní ojú òpópónà,ní àwọn òrùlé àti àwọn gbàgede àkójọwọ́n pohùnréré,Wọ́n dọ̀bálẹ̀ pẹ̀lú ẹkún.

Ka pipe ipin Àìsáyà 15

Wo Àìsáyà 15:3 ni o tọ