Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 13:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnikẹ́ni tí a bá gbámú ni a ó wọ́ nílẹ̀ tuurutu,gbogbo àwọn tí ọwọ́ bá tẹ̀ ni yóò ti ipa idà kú.

Ka pipe ipin Àìsáyà 13

Wo Àìsáyà 13:15 ni o tọ