Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 11:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn yóò dìgbòlu àwọn gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́Fílísítíà ni apá ìwọ̀ oòrùn,wọn yóò pawọ́pọ̀ kọlu àwọnènìyàn apá ìlà oòrùn.Wọn yóò gbé ọwọ́ọ wọn lé Édómù àti Móábù,àwọn ará Ámónì yóò sì di ìwẹ̀fàa wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 11

Wo Àìsáyà 11:14 ni o tọ