Bí ènìyàn tií tọwọ́ bọ ìtẹ́ ẹyẹ,bẹ́ẹ̀ ni ọwọ́ọ̀ mi tẹ ọrọ̀ àwọn orílẹ̀ èdè.Bí ènìyàn tii kó ẹyin tí a kọ̀ sílẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni mo kó àwọn orílẹ̀ èdèkò sí èyí tí ó fapálupá,tàbí kí ó ya ẹnu láti dún.’ ”