Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbọ́ ẹ̀yin ọ̀run! Fi etí sílẹ̀, ìwọ ayé!Nítorí Olúwa ti sọrọ̀:“Mo tọ́ àwọn ọmọ dàgbà,Ṣùgbọ́n wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi.

Ka pipe ipin Àìsáyà 1

Wo Àìsáyà 1:2 ni o tọ