Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 8:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn ará Síríà ti Dámásíkù sì wá láti ran Hadadésérì ọba Sóbà lọ́wọ́, Dáfídì sì pa ẹgbàámọ́kànlá ènìyàn nínú àwọn ará Síríà.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 8

Wo 2 Sámúẹ́lì 8:5 ni o tọ