Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 5:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì ṣe, nígbà tí ìwọ bá gbọ́ ìró ẹṣẹ̀ lórí àwọn igi Bákà náà, nígbà náà ni ìwọ yóò sì yára, nítorí pé nígbà náà ni Olúwa yóò jáde lọ níwájú rẹ láti kọlù ogun àwọn Fílístínì.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 5

Wo 2 Sámúẹ́lì 5:24 ni o tọ