Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 21:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Ọba dá Méfíbóṣétì sí, ọmọ Jónátanì, ọmọ Ṣọ́ọ̀lù, nítorí ìbúra Olúwa tí ó wà láàrin Dáfídì àti Jónátánì ọmọ Sọ́ọ̀lù.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 21

Wo 2 Sámúẹ́lì 21:7 ni o tọ