Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 21:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mú ọkùnrin méje nínú àwọn ọmọ rẹ̀ fún wá, àwa ó sì so wọ́n rọ̀ fún Olúwa ní Gíbéà ti Ṣọ́ọ̀lù ẹni tí Olúwa ti yàn.”Ọba sì wí pé, “Èmi ó fi wọ́n fún yín.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 21

Wo 2 Sámúẹ́lì 21:6 ni o tọ