Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 15:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnìkan sì sọ fún Dáfídì pé, “Áhítófélì wà nínú àwọn asọ̀tẹ̀ pẹ̀lù Ábúsálómù.” Dáfídì sì wí pé, “Olúwa, èmi bẹ̀ ọ́, sọ ìmọ̀ Áhítófélì di asán.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 15

Wo 2 Sámúẹ́lì 15:31 ni o tọ