Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 15:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì wí fún Sádókù àlùfáà pé, “Aríran ha kọ́ ni ọ́? Padà sí ìlú ní àlàáfíà, àti àwọn ọmọ rẹ méjèèjì pẹ̀lú rẹ, Áhímásì ọmọ rẹ, àti Jónátanì ọmọ Ábíátárì.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 15

Wo 2 Sámúẹ́lì 15:27 ni o tọ