Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 15:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sì wò ó, Sádókù pẹ̀lú àti gbogbo àwọn ọmọ Léfì tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ sí ń ru àpótí-ẹ̀rí Ọlọ́run: wọ́n sì gbé àpótí-ẹ̀rí Ọlọ́run náà sọ̀kalẹ̀; Ábíátarì sí gòkè, títí gbogbo àwọn ènìyàn sì fi dẹ́kun àti máa kọjá láti ìlú wá.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 15

Wo 2 Sámúẹ́lì 15:24 ni o tọ