Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 15:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Ábúsálómù rán àmì sáàrin gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì pé, “Nígbà tí ẹ̀yin bá gbọ́ ìró ìpè, kí ẹ̀yin sì wí pé, ‘Ábúsálómù jọba ní Hébúrónì.’ ”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 15

Wo 2 Sámúẹ́lì 15:10 ni o tọ