Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 12:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì kó àwọn ènìyàn náà tí ó wà nínú rẹ̀, ó sì fi wọ́n sí iṣẹ́ ayùn, àti sí iṣẹ́ nǹkan ìtùlẹ̀ tí a fi irin ṣe, àti sí iṣẹ́ àáké irin, ó sì fi wọ́n sí iṣẹ́ bíríkì ṣíṣe: bẹ́ ẹ̀ náà ni òun sì ṣe sí gbogbo ìlú àwọn ọmọ Ámónì. Dáfídì àti gbogbo àwọn ènìyàn náà sì padà sí Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 12

Wo 2 Sámúẹ́lì 12:31 ni o tọ