Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 12:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí pé, “Nígbà tí ọmọ náà ń bẹ láàyè, èmi gbààwẹ̀, èmi sì sunkún: nítorí tí Èmi wí pé, ‘Ta ni ó mọ̀ bí Ọlọ́run ó ṣàánú mi, kí ọmọ náà le yè.’

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 12

Wo 2 Sámúẹ́lì 12:22 ni o tọ