Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 12:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ sì bí léèrè pé, “Kí lèyí tí ìwọ ṣe yìí? Nítorí ọmọ náà nígbà tí ó ń bẹ láàyè ìwọ gbààwẹ̀, o sì sunkún; ṣùgbọ́n nígbà tí ọmọ náà kú, ó dìde ó sì jẹun.”

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 12

Wo 2 Sámúẹ́lì 12:21 ni o tọ