Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 11:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọkùnrin ìlú náà sì jáde wá, wọ́n sì bá Jóábù jà: díẹ̀ sì ṣubú nínú àwọn ènìyàn náà nínú àwọn ìránṣẹ́ Dáfídì, Ùráyà ará Hítì sì kú pẹ̀lú.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 11

Wo 2 Sámúẹ́lì 11:17 ni o tọ