Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 10:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí àwọn ọmọ Ámónì sì ríi pé àwọn ará Síríà sá, àwọn pẹ̀lú sì sá níwájú Ábíṣáì, wọ́n sì wọ inú ìlú lọ. Jóábù sì padà kúrò lẹ́yìn àwọn ọmọ Ámónì, ó sì wá sí Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 10

Wo 2 Sámúẹ́lì 10:14 ni o tọ