Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kẹta, ọkùnrin kan dé láti ibi ibùdó Ṣọ́ọ̀lù, pẹ̀lú aṣọ rẹ̀ tí ó ti ya; àti erùpẹ̀ ní orí rẹ̀. Nígbà tí ó dé ọ̀dọ̀ Dáfídì, ó wólẹ̀ fún un láti bu ọlá fún un.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 1

Wo 2 Sámúẹ́lì 1:2 ni o tọ