Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Sámúẹ́lì 1:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n ṣọ̀fọ̀, wọ́n sì sunkún, wọ́n sì gbààwẹ̀ títí di ìrọ̀lẹ́ fún Ṣọ́ọ̀lù àti ọmọ rẹ̀ Jónátanì àti fún àwọn ọmọ ogun Olúwa, àti fún àwọn ilé Ísírẹ́lì, nítorí wọ́n ti ṣubú nípa idà.

Ka pipe ipin 2 Sámúẹ́lì 1

Wo 2 Sámúẹ́lì 1:12 ni o tọ