Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 9:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n jáde lọ láti lọ sin-ín, wọn kò rí nǹkankan àyàfi agbárí i rẹ̀, ẹsẹ̀ rẹ̀ méjèèjì àti ọwọ́ ọ rẹ̀ méjèèjì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 9

Wo 2 Ọba 9:35 ni o tọ