Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 9:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Fi ìwọ̀ kọ́ kẹ̀kẹ́ ogun mi.” Jórámù pa á láṣẹ. Àti nígbà tí a fi kọ́, Jórámù ọba Ísírẹ́lì àti Áhásáyà ọba Júdà, gun kẹ̀kẹ́ lọ, olúkúlùkù nínú kẹ̀kẹ́ ogun tirẹ̀, láti lọ bá Jéhù. Wọ́n bá a pàdé ní ibi oko tí ó ti jẹ́ ti Nábótì ará Jéṣírẹ́lì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 9

Wo 2 Ọba 9:21 ni o tọ