Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 8:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Gèhásì ti ń sọ bí tí Èlíṣà ṣe jí òkú di alàyè, obìnrin náà tí ọmọ rẹ̀ ọkùnrin tí Èlíṣà ti dá padà sí ayé wá láti bẹ ọba fún ilé àti ilẹ̀ rẹ̀.Gèhásì sì wí pé, “Obìnrin náà nì yí Olúwa mi ọba, ọmọkùnrin rẹ náà nìyí tí Èlísà ti jí dìde sí ayé.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 8

Wo 2 Ọba 8:5 ni o tọ