Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 8:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, nítorí ti ìránṣẹ́ rẹ̀ Dáfídì. Olúwa kò fẹ́ pa Júdà run, ó ti ṣèlérí láti ṣètọ́jú ìmọ́lẹ́ fún Dáfídì àti àwọn ilé rẹ̀ títí láéláé.

Ka pipe ipin 2 Ọba 8

Wo 2 Ọba 8:19 ni o tọ