Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 8:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísin yìí, Èlíṣà wí fún obìnrin náà tí ọmọ rẹ̀ ọkùnrin jí pàdà sáyé pé, “jáde lọ pẹ̀lú ìdílé rẹ kí o sì lọ dúró fún ìgbà díẹ̀ ní ibíkíbi tí o bá le dúró sí, nítorí Olúwa ti pàṣẹ ìyàn ní ìlú tí yóò lò tó ọdún méje.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 8

Wo 2 Ọba 8:1 ni o tọ