Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 7:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísìn yìí ọba sì mú ìjòyè náà lórí ẹni tí ó fi ọwọ́ ara rẹ̀ tì ní ìkáwọ́ ẹnu ibodè, àwọn ènìyàn sì tẹ̀ẹ́ mọ́lẹ̀ ní ẹnu ibodè. Ó sì kú, gẹ́gẹ́ bí ènìyàn Ọlọ́run ti ṣọ tẹ́lẹ̀ nígbà tí ọba sọ̀kalẹ̀ lọ sí ilé rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 7

Wo 2 Ọba 7:17 ni o tọ