Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 6:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì dá a lóhùn pé, “Tí Olúwa kò bá ràn ọ́ lọ́wọ́, níbo ni èmi ti lè rí ìrànlọ́wọ́ láti ọ̀dọ̀ rẹ̀? Láti inú ilé ìpakà? Láti inú ibi ìfúntí?”

Ka pipe ipin 2 Ọba 6

Wo 2 Ọba 6:27 ni o tọ