Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 6:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni ó pèṣè àṣè ńlá fún wọn, lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n jẹ tí wọ́n mu, ó sì rán wọn lọ, wọ́n sì padà sí ọ̀dọ̀ ọ̀gá wọn. Bẹ́ẹ̀ ni ẹgbẹ́ láti Árámù dáwọ́ ìgbógun ti ilẹ̀ Ísírẹ́lì dúró.

Ka pipe ipin 2 Ọba 6

Wo 2 Ọba 6:23 ni o tọ