Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 6:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíṣà sọ fún wọn pé “Èyí kì í ṣe ọ̀nà bẹ́ẹ̀ ni èyí kì í ṣe ìlú náà. Tẹ̀lé mi, èmi yóò mú u yín lọ sí ọ̀dọ̀ ọkùnrin tí ẹ̀yin ń wá.” Ó sì sìn wọ́n lọ sí Samáríà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 6

Wo 2 Ọba 6:19 ni o tọ