Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 6:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kò sí ọ̀kan nínú wa, Olúwa ọba mi,” ọ̀kan lára ìránṣẹ́ rẹ̀ sì wí pé, “ṣùgbọ́n Èlíṣà, wòlíì tí ó wà ní Ísírẹ́lì, sọ fún ọba Ísírẹ́lì ọ̀rọ̀ gangan tí ó sọ nínú yàrá rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 6

Wo 2 Ọba 6:12 ni o tọ