Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 5:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ọba Ísírẹ́lì ti ka ìwé náà ó fa aṣọ rẹ̀ ya, ó sì wí pé, “Èmi ha jẹ́ Ọlọ́run? Ǹjẹ́ èmi le pa kí n sì mú wá sí àyè padà? Kí ni ó dé tí eléyìí rán ènìyàn sí mi láti wo àrùn ẹ̀tẹ̀ rẹ sàn, kí ẹ wo bí ó ti ń wá ọ̀nà láti wá ìjà pẹ̀lú mi!”

Ka pipe ipin 2 Ọba 5

Wo 2 Ọba 5:7 ni o tọ