Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 5:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Tí o kò bá ní gba,” Námánì wí pé, “Jọ̀wọ́ jẹ́ kí èmi, ìránṣẹ́ rẹ fi fún ọ gẹ́gẹ́ bí ọ̀pọ̀ ilẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹrù ẹrùpẹ̀ ìbaka méjì, nítorí láti òní lọ ìránṣẹ́ rẹ kì yóò rú ẹbọ sísun àti rúbọ sí ọ̀kan lára àwọn ọlọ́run mìíràn ṣùgbọ́n Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Ọba 5

Wo 2 Ọba 5:17 ni o tọ