Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 5:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wòlíì náà dáhùn pé, “Gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti ń bẹ láàyè, ẹni tí mo ń sìn, èmi kò ní gba ohun kan,” Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Námánì rọ̀ ọ́ láti gbàá, ó kọ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 5

Wo 2 Ọba 5:16 ni o tọ