Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 5:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíṣà rán ìránṣẹ́ láti lọ sọ fún un pé, “Lọ, wẹ̀ ara rẹ ní ìgbà méje ní odò Jọ́dánì, ẹran ara rẹ yóò sì tún padà bọ̀ sípò, ìwọ yóò sì mọ́.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 5

Wo 2 Ọba 5:10 ni o tọ