Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 4:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wọlé, ó sì kúnlẹ̀ ṣíwájú ẹṣẹ̀ rẹ̀ ó sì tẹ̀ Orí sílẹ̀. Nígbà náà ó sì mú ọmọ rẹ̀ ó sì jáde lọ.

Ka pipe ipin 2 Ọba 4

Wo 2 Ọba 4:37 ni o tọ