Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 4:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíṣà sì pe Géhásì ó sì wí pé, “Pe ará Súnémù.” Ó sì ṣe bẹ́ẹ̀. Nígbà tí ó dé, ó wí pé, “Gba ọmọ rẹ.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 4

Wo 2 Ọba 4:36 ni o tọ