Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 4:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Géhásì sì ń lọ síbẹ̀ ó sì fi ọ̀pá náà lé ojú ọmọ náà, ṣùgbọ́n kò sí ohùn dídún. Bẹ́ẹ̀ ni Géhásì padà lọ láti lọ bá Èlíṣà láti sọ fún un pé, “Ọmọ ọkùnrin náà kò tí ì dìde.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 4

Wo 2 Ọba 4:31 ni o tọ