Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 3:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yóò sì bi gbogbo ìlú olódí àti gbogbo àgbà ìlú ṣubú. Ìwọ yóò sì gé gbogbo igi dáradára ṣubú, dá gbogbo orísun omi dúró, kí o sì pa gbogbo pápá dáradára pẹ̀lú òkúta run.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 3

Wo 2 Ọba 3:19 ni o tọ