Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 25:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olórí àwọn ọ̀sọ́ sì mú gẹ́gẹ́ bí olórí àwọn ẹlẹ́wọ̀n Ṣéráíáyà olórí àwọn àlùfáà, Ṣéfáníà àlùfáà ẹni tí ó kù nínú oyè gíga àti àwọn olùṣọ́nà mẹ́ta.

Ka pipe ipin 2 Ọba 25

Wo 2 Ọba 25:18 ni o tọ