Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 24:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí ìbínú Olúwa, ni gbogbo èyí ṣe sẹ sí Jérúsálẹ́mù, àti Júdà, ní òpin ó ta wọ́n nù kúrò níwájú rẹ̀.Nísinsìn yìí Ṣedekíàyà sì ṣọ̀tẹ̀ sí ọba Bábílónì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 24

Wo 2 Ọba 24:20 ni o tọ