Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 24:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣedekáyà jẹ́ ẹni ọdún mọ́kànlélógún nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ṣe ìjọba, ó sì jẹ ọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún mọ́kànlá. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Hámútalì ọmọbìnrin Jeremáyà; ó sì wá láti Líbínà.

Ka pipe ipin 2 Ọba 24

Wo 2 Ọba 24:18 ni o tọ