Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 24:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ti kọ́ fún Olúwa, Ó kó wọn lọ sí ìgbékùn gbogbo Jérúsálẹ́mù: gbogbo ìjòyè àti àwọn akọni alágbára ọkùnrin, àti gbogbo oníṣọ̀nà àti ọlọ́nà tí àpapọ̀ rẹ̀ jẹ́ ẹgbàárún ún, àwọn talákà ènìyàn ilẹ̀ náà nìkan ni ó kù.

Ka pipe ipin 2 Ọba 24

Wo 2 Ọba 24:14 ni o tọ